News

Lẹyin iku Poopu to wa lori alefa ni wọn maa n yan Poopu miran. Wọn tun maa n yan Poopu mii ti Poopu naa ba kọwe fi ipo rẹ silẹ gẹgẹ bi Pope Benedict XVI ṣe ṣe lọdun 2013.